2 episodes

1- Se awa Musulumi ni eto Kankan lori ile Filistin? Kinni awon igbiyanju ti awon asaaju Musulumi ti se ninu itan lori ile Filistin? Nje awa Musulumi aye ode oni ni igbiyanju kan lati se bi lori ati so ile Filistin di ile ominira fun Musulumi papaajulo masalaasi Kudusi? Gbogbo awon ibeere wonyi ni a o ri idahun fun ninu ibanisoro yi.
2- Apa keji ibanisoro yi so nipa awon ogbon arekereke ti awon Yahudi lo lati fi gba ile Filistin ti won si le awon ti won ni ile kuro, bakannaa ni oro waye lori itumo Yahudi ati ipile gbolohun naa.

Ohun Ti O Leto Fun Musulumi Lati Mo nipa Ile Filistin Isa Akindele Solahudeen

  • Islam

1- Se awa Musulumi ni eto Kankan lori ile Filistin? Kinni awon igbiyanju ti awon asaaju Musulumi ti se ninu itan lori ile Filistin? Nje awa Musulumi aye ode oni ni igbiyanju kan lati se bi lori ati so ile Filistin di ile ominira fun Musulumi papaajulo masalaasi Kudusi? Gbogbo awon ibeere wonyi ni a o ri idahun fun ninu ibanisoro yi.
2- Apa keji ibanisoro yi so nipa awon ogbon arekereke ti awon Yahudi lo lati fi gba ile Filistin ti won si le awon ti won ni ile kuro, bakannaa ni oro waye lori itumo Yahudi ati ipile gbolohun naa.

  Ohun Ti O Leto Fun Musulumi Lati Mo nipa Ile Filistin -1

  • 51 min
  Ohun Ti O Leto Fun Musulumi Lati Mo nipa Ile Filistin -2

Top Podcasts In Islam